Written by Tòmíwá Olúyínká
Rev’d Dr. Tunji Bamgbose as always, preached Jesus, this time focusing on the assurance of our glorification as exemplified in Christ Jesus through His glorification. He titled the sermon: Chosen for Glorification, highlighting these declarations from the following bible texts: John 17 and Matthew 5:1-9.
Declaring these truths are good, however, it is not enough to solely claim them. Rev’d reminded the church of our responsibilities, as believers, to enter into the glory of God:
He further stressed that “you’re chosen to be glorified by God only if you’re born again, if you believe in the manifestation of God in Christ Jesus, and if you believe in the name of Jesus.”
In closing, Jesus freely gave his life up for us and intercedes on our behalf to God. With this truth, Rev’d Bamgbose asked the church, “why should you doubt your importance in this world and your glorification in Christ Jesus?”
Church, jack up your faith in Christ!
Experience the full sermon here
Written by Tòmíwá Olúyínká
Written by Kelani Omótóyòsí
Omowe, Alufa. Tunji Bamgbose, gẹ́gẹ́ bí gbogbo igba, se iwàásù nípa Jésù. Ní ìgbà yìí won dalori ìdánilójú igbelogo wa gẹ́gẹ́ bí a ṣe rí i nínú Kristi Jésù nípasẹ̀ igbelogo rẹ̀. Ó pè àkori ìwàásù náà ní: “Yiyàn fún Igbelogo”, wón sì mu àwọn òtító wọ̀nyí láti inú àwọn ìwé Mímọ́ yìí: Johannu orí metadinlogun àti Mátíù orí kaarun, ese kini de ikesan
Siso àwọn òtítọ́ wọ̀nyí dára gan-an, ṣùgbọ́n ko to láti máa sọ wọ́n lásán. Alufa tún rán ìjọ leti nípa ojúṣe wa gẹ́gẹ́ bí àwọn onígbàgbọ́, láti wọ inú ògo Ọlọ́run.
Won tún tẹnumọ́ pé, “a yàn ẹ́ láti jẹ́ ẹni tí Ọlọ́run yóò ṣe lógo bi o ba je eni atúnbí sílẹ̀, bí o bá gbàgbọ́ nínú ìfarahàn Ọlọ́run nínú Kristi Jésù, àti bí o bá sì gbàgbọ́ nínú orúkọ Jésù.”
Ní ìparí, Jésù fi emi rẹ̀ lele l’ofe fun wa, ó tún gbadura fun wa si Ọlọ́run. Nípa òtítọ́ yìí, Alufa Bamgbósè bi ìjọ pé, “kí ló dé tí ẹ fi máa fi ṣiyèméjì ti o se pàtàkì nínú ayé yìí àti igbelogo tí a fún yín nínú Kristi Jésù?”
Ìjọ, ẹ ji ìgbàgbọ́ yín nínú Kristi Jésù!
E wo iwasu lekun rere nibi.
Written by Kelani Omótóyòsí
2 Comments
túndé
February 5, 2026When Rev’d said you won’t get to know the deep things of God until you choose to come up the mountain with Jesus, I felt it.
This life of faith no be beans fr, na real hard work like climbing mountain.
fesbachchurch
February 9, 2026Absolutely! May God keep working in and on us to give us the desire and the power.(Amen)